Jẹ́nẹ́sísì 15:13 BMY

13 Nígbà náà ni Olúwa wí fún un pé, “Mọ èyí dájú pé, àwọn ìran rẹ yóò ṣe àtìpó ní orílẹ̀ èdè tí kì í ṣe ti wọn, a ó kó wọn lẹ́rú, a ó sì jẹ wọ́n ní ìyà fún irínwó ọdún (400).

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15

Wo Jẹ́nẹ́sísì 15:13 ni o tọ