Jẹ́nẹ́sísì 15:18 BMY

18 Ní ọjọ́ náà gan-an ni Olúwa dá májẹ̀mú pẹ̀lú Ábúrámù, ó sì wí pé, “Àwọn ìran rẹ ni èmi yóò fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Éjíbítì dé odò ńlá Yúfúrátè:

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15

Wo Jẹ́nẹ́sísì 15:18 ni o tọ