Jẹ́nẹ́sísì 15:9 BMY

9 Nítorí náà, Olúwa wí fún-un pé, “Mú abo màlúù, ewúrẹ́ àti àgbò ọlọ́dún mẹ́tamẹ́ta wá, àti àdàbà kan àti ọmọ ẹyẹlé kan.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 15

Wo Jẹ́nẹ́sísì 15:9 ni o tọ