Jẹ́nẹ́sísì 16:11 BMY

11 Ańgẹ́lì náà sì wí fún un pé,“Ìwọ ti lóyún ìwọ yóò sì bíọmọkùnrin kan,ìwọ yóò sì pe orúkọ rẹ̀ ní Íṣímáélì,nítorí tí Olúwa ti rí ìpọ́njú rẹ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:11 ni o tọ