Jẹ́nẹ́sísì 16:14 BMY

14 Nítorí náà ni a ṣe ń pe kànga náà ní Beeri-Lahai-Róì: kànga ẹni alààyè tí ó rí mi. Ó wà lágbedeméjì Kédásì àti Bérédì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:14 ni o tọ