Jẹ́nẹ́sísì 16:4 BMY

4 Ábúrámù sì bá Ágárì lòpọ̀, ó sì lóyún.Nígbà tí ó sì ti mọ̀ pé òun lóyún, ó bẹ̀rẹ̀ sì ní kẹ́gàn ọ̀gá rẹ̀ (Ṣáráì).

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:4 ni o tọ