Jẹ́nẹ́sísì 16:8 BMY

8 Ó sì wí pé, “Hágárì, ìránṣẹ́ Ṣáráì, níbo ni o ti ń bọ̀, níbo sì ni ìwọ ń lọ?”Ó sì dáhùn pé, “Mo ń sá lọ kúrò lọ́dọ̀ ọ̀gá mi Ṣáráì ni.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 16

Wo Jẹ́nẹ́sísì 16:8 ni o tọ