Jẹ́nẹ́sísì 17:1 BMY

1 Ní ìgbà tí Ábúrámù di ẹni ọ̀kàndínlọ́gọ́rùnún (99) ọdún, Olúwa farahàn án, ó sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run alágbára, máa rìn níwájú mi, kí o sì jẹ́ aláìlábùkù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 17

Wo Jẹ́nẹ́sísì 17:1 ni o tọ