Jẹ́nẹ́sísì 17:18 BMY

18 Ábúráhámù sì wí fún Ọlọ́run pé, “Ṣá à jẹ́ kí Ísímáélì kí ó wà láàyè lábẹ́ ìbùkún rẹ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 17

Wo Jẹ́nẹ́sísì 17:18 ni o tọ