Jẹ́nẹ́sísì 17:9 BMY

9 Nígbà náà ni Ọlọ́run wí fún Ábúráhámù pé, “Ìwọ máa pa májẹ̀mú mí mọ́, ìwọ àti irú ọmọ rẹ lẹ́yìn rẹ àti àwọn ìran tí ó ń bọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 17

Wo Jẹ́nẹ́sísì 17:9 ni o tọ