19 Nítorí tí èmi ti yàn án láti kọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ àti àwọn ará ilé rẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀, láti máa pa ọ̀nà Olúwa mọ nípa ṣíṣe olóòtọ́ àti olódodo: kí Olúwa le è mú ìlérí rẹ̀ fún Ábúráhámù ṣẹ.”
Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18
Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:19 ni o tọ