Jẹ́nẹ́sísì 18:22 BMY

22 Àwọn ọkùnrin náà yí padà, wọ́n sì ń lọ sí ìhà Ṣódómù. Ṣùgbọ́n Ábúráhámù dúró níbẹ̀ níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18

Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:22 ni o tọ