Jẹ́nẹ́sísì 18:24 BMY

24 “Bí ó bá ṣe pé Ìwọ rí àádọ́ta olódodo nínú ìlú náà, Ìwọ yóò ha run-ún, Ìwọ kì yóò ha dá ìlú náà sí nítorí àwọn àádọ́ta olódodo tí ó wà nínú rẹ̀ náà?

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18

Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:24 ni o tọ