Jẹ́nẹ́sísì 18:28 BMY

28 bí ó bá ṣe pe olódodo márùn-dín-làádọ́ta (45) ni ó wà nínú ìlú, Ìwọ yóò ha pa ìlú náà run nítorí ènìyàn márùn-ún bí?” Olúwa dáhùn pé, “Èmi kì yóò pa ìlú náà run bí mo bá rí olódodo márùn-dín-láàádọ́ta nínú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18

Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:28 ni o tọ