Jẹ́nẹ́sísì 18:32 BMY

32 Ábúráhámù sì wí pé, “Jọ̀wọ́ má ṣe bínú Olúwa. Jẹ́ kí ń béèrè lẹ́ẹ̀kan si. Bí ó bá ṣe pé ènìyàn mẹ́wàá ni bá tí ó jẹ́ olódodo ńkọ́?” Olúwa wí pé, “Nítorí ènìyàn mẹ́wàá náà, Èmi kì yóò pa á run.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 18

Wo Jẹ́nẹ́sísì 18:32 ni o tọ