Jẹ́nẹ́sísì 19:1 BMY

1 Ní àsáálẹ́, àwọn ańgẹ́lì méjì sì wá sí ìlú Ṣódómù, Lọ́tì sì jókòó ní ẹnu ibodè ìlú. Bí ó sì ti rí wọn, ó sì dide láti pàdé wọn, ó kí wọn, ó sí foríbalẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 19

Wo Jẹ́nẹ́sísì 19:1 ni o tọ