Jẹ́nẹ́sísì 19:25 BMY

25 Báyìí ni ó run àwọn ìlú náà àti gbogbo ilẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú gbogbo àwọn tí ó wà ní ìlú ńláńlá wọ̀n-ọn-nì àti ohun gbogbo tí ó hù jáde nílẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 19

Wo Jẹ́nẹ́sísì 19:25 ni o tọ