Jẹ́nẹ́sísì 19:28 BMY

28 Ó sì wo ìhà Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ilẹ̀ pẹ̀tẹ́lẹ̀ wọ̀n-ọn-nì, ó sì rí èéfín tí ń ti ibẹ̀ jáde bí èéfín iná ìléru.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 19

Wo Jẹ́nẹ́sísì 19:28 ni o tọ