Jẹ́nẹ́sísì 19:32 BMY

32 Wá, jẹ́ kí a mú bàbá wa mu ọtí yó, kí ó ba à le bá wa lò pọ̀, kí àwa kí ó lè bí ọmọ, kí ìran wa má ba à parẹ́.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 19

Wo Jẹ́nẹ́sísì 19:32 ni o tọ