Jẹ́nẹ́sísì 2:11 BMY

11 Orúkọ èkínní ni Písónì: òun ni ó sàn yí gbogbo ilẹ̀ Háfílà ká, níbi tí wúrà gbé wà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2

Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:11 ni o tọ