Jẹ́nẹ́sísì 2:13 BMY

13 Orúkọ odò kejì ni Gíhónì: òun ni ó sàn yí gbogbo ilẹ̀ Kúsì ká.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2

Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:13 ni o tọ