Jẹ́nẹ́sísì 2:20 BMY

20 Gbogbo ohun ọ̀sìn, ẹyẹ ojú ọ̀run àti gbogbo ẹranko igbó ni ọkùnrin náà sọ ní orúkọ.Ṣùgbọ́n fún Ádámù ni a kò rí olùrànlọ́wọ́ tí ó rí bí i rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2

Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:20 ni o tọ