23 Ọkùnrin náà sì wí pé,“Èyí ni egungun láti inú egungun miàti ẹran-ara nínú ẹran-ara mi;‘obìnrin’ ni a ó máa pè énítorí a mú un jáde láti ara ọkùnrin.”
Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2
Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:23 ni o tọ