Jẹ́nẹ́sísì 2:3 BMY

3 Ọlọ́run sì súre fún ọjọ́ kéje, ó sì yà á sí mímọ́, nítorí pé ní ọjọ́ náà ni ó sinmi kúrò nínú iṣẹ́ dídá ayé tí ó ti ń ṣe.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2

Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:3 ni o tọ