Jẹ́nẹ́sísì 2:7 BMY

7 Olúwa Ọlọ́run sì mọ ènìyàn láti ara erùpẹ̀ ilẹ̀, ó si mí èémí sí ihò imú rẹ̀, èémí ìyè, ènìyàn sì di ẹ̀dá alààyè.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 2

Wo Jẹ́nẹ́sísì 2:7 ni o tọ