Jẹ́nẹ́sísì 20:13 BMY

13 Nígbà tí Ọlọ́run sì mú mi rìn kiri kúrò ní ilé baba mi, mo wí fún un pé, ‘Èyí ni ọ̀nà tí ó lè gbà fi hàn pé ó fẹ́ràn mi: Gbogbo ibi tí a bá dé máa sọ pé, “Arákùnrin rẹ ni mí.” ’ ”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 20

Wo Jẹ́nẹ́sísì 20:13 ni o tọ