Jẹ́nẹ́sísì 20:2 BMY

2 Ábúráhámù sì sọ ní ti Ṣárà aya rẹ̀ níbẹ̀ pé, “Arábìnrin mi ni.” Ábímélékì ọba Gérárì sì ránṣẹ́ mú Ṣárà wá sí ààfin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 20

Wo Jẹ́nẹ́sísì 20:2 ni o tọ