Jẹ́nẹ́sísì 20:5 BMY

5 Ǹjẹ́ òun kò sọ fún mi pé, ‘Arábìnrin mi ni,’ obìnrin náà pẹ̀lú sì sọ pé, ‘arákùnrin mí ni’? Ní òtítọ́ pẹ̀lú ọ̀kàn mímọ́ àti ọwọ́ mímọ́, ni mo ṣe èyí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 20

Wo Jẹ́nẹ́sísì 20:5 ni o tọ