10 ó sì wí fún Ábúráhámù pé, “Lé ẹrúbìnrin yìí àti ọmọ rẹ̀ jáde, nítorí ọmọ ẹrú yìí kò ní bá ọmọ mi Ísáákì pín ogún.”
Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21
Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:10 ni o tọ