Jẹ́nẹ́sísì 21:12 BMY

12 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run wí fun un pé, “Má ṣe ba ọkàn jẹ́ nítorí ọmọ náà àti ẹrúbìnrin rẹ. Gbọ́ ohun tí Ṣárà wí fún ọ, nítorí nípasẹ̀ Ísáákì ni a ó ti ka irú ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21

Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:12 ni o tọ