Jẹ́nẹ́sísì 21:14 BMY

14 Ábúráhámù sì dìde ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, ó sì mú oúnjẹ àti ìgò omi kan, ó sì kó wọn fún Ágárì, ó kó wọn lé e léjìká, ó sì lé e jáde pẹ̀lú ọmọ náà. Ó sì lọ lọ́nà rẹ, ó sì ń ṣe alárìnkiri ní ijù Báá-Ṣébà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21

Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:14 ni o tọ