Jẹ́nẹ́sísì 21:16 BMY

16 Ó sì lọ, ó sì jókòó nítòòsí ibẹ̀, níwọ̀n bí ìtafà (bí i ogójì míta), nítorí, ó rò ó nínú ara rẹ̀ pé, “Èmi kò fẹ́ wo bí ọmọ náà yóò ṣe kú.” Bí ó sì ti jókòó sí tòòsí ibẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní sunkún.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 21

Wo Jẹ́nẹ́sísì 21:16 ni o tọ