Jẹ́nẹ́sísì 22:12 BMY

12 Ańgẹ́lì Olúwa sì wí pé, “Má ṣe fọwọ́ kan ọmọ náà, ìwọ kò sì gbọdọ̀ ṣe é ni ohun kan. Nísinsin yìí ni mo mọ̀ pé o bẹ̀rù Ọlọ́run, nítorí pé ìwọ kò fi ọmọ rẹ, àní, ọmọ rẹ kan soso dùn mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:12 ni o tọ