Jẹ́nẹ́sísì 22:19 BMY

19 Nígbà náà ni Ábúráhámù padà tọ àwọn ìrànṣẹ́ rẹ̀ lọ. Gbogbo wọn sì padà lọ sí Báá-Ṣébà Ábúráhámù sì dúró ní Báá-Ṣébà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 22

Wo Jẹ́nẹ́sísì 22:19 ni o tọ