Jẹ́nẹ́sísì 23:11 BMY

11 pé, “Rárá, Olúwa mi, Gbọ́ tèmi; mo fún ọ ní ilẹ̀ náà àti ihò àpáta tí ó wà níbẹ̀. Mo fún ọ níwájú gbogbo àwọn ènìyàn mi. Sin òkú rẹ ṣíbẹ̀.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 23

Wo Jẹ́nẹ́sísì 23:11 ni o tọ