Jẹ́nẹ́sísì 23:6 BMY

6 “Olúwa mi, gbọ́ tiwa, ó jẹ́ alágbára ọmọ-aládé láàrin wa, sin òkú rẹ sí ibojì tí ó dárajù nínú àwọn ibojì wa, kò sí ẹni tí yóò fi ibojì rẹ dùn ọ́ láti sin òkú rẹ sí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 23

Wo Jẹ́nẹ́sísì 23:6 ni o tọ