Jẹ́nẹ́sísì 24:16 BMY

16 Ọmọbìnrin náà rẹwà, wúndíá ni, kò sì tíì mọ ọkùnrin, ó lọ sí ibi ìsun omi náà, ó sì pọn omi sínú ìkòkò omi, ó sì gbé e, ó ń gòkè bọ̀ kúrò níbi omi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:16 ni o tọ