Jẹ́nẹ́sísì 24:46 BMY

46 “Kíákíá ni ó sọ ìkòkò rẹ̀ kalẹ̀ láti èjìká rẹ̀, ó sì wí fún mi pé, ‘Mu ún, èmi yóò sì tún fún àwọn ràkúnmí rẹ mu pẹ̀lú.’ Mo sì mu, ó sì tún fún àwọn ràkúnmí mi mu pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:46 ni o tọ