Jẹ́nẹ́sísì 24:48 BMY

48 Mo sì wólẹ̀ mo sì sin Olúwa, Ọlọ́run Ábúráhámù olúwa à mi, ẹni tí ó ṣe amọ̀nà mi láti rí ọmọ ọmọ arákùnrin olúwa mi, mú wá fún ọmọ rẹ̀ (Ísáákì).

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:48 ni o tọ