Jẹ́nẹ́sísì 24:53 BMY

53 Nígbà náà ni ó kó ohun èlò wúrà àti fàdákà jáde àti aṣọ, ó sì fi wọ́n fún Rèbékà, ó fún arákùnrin Rèbékà àti ìyá rẹ̀ ní ẹ̀bùn olówó iyebíye pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:53 ni o tọ