Jẹ́nẹ́sísì 24:55 BMY

55 Ṣùgbọ́n arákùnrin Rèbékà àti ìyá rẹ̀ fèsì pé, “A fẹ́ kí Rèbékà wà pẹ̀lú wa fún nǹkan bí ọjọ́ mẹ́wàá sí i, lẹ́yìn ìyẹn, ìwọ le máa mu lọ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 24

Wo Jẹ́nẹ́sísì 24:55 ni o tọ