Jẹ́nẹ́sísì 25:10 BMY

10 Inú oko tí Ábúráhámù rà lọ́wọ́ ara Hítì yìí ni a sin Ábúráhámù àti Ṣárà aya rẹ̀ sí.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25

Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:10 ni o tọ