Jẹ́nẹ́sísì 25:23 BMY

23 Olúwa sì wí fún un pé,“Orílẹ̀ èdè méjì ni ń bẹ nínú rẹ,àwọn méjì tí ó jáde láti inú rẹ yóò sì pínyà,àwọn ènìyàn kan yóò jẹ́ alágbára ju èkejì lọ,ẹ̀gbọ́n yóò sì máa sin àbúrò.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25

Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:23 ni o tọ