Jẹ́nẹ́sísì 25:25 BMY

25 Èyí tí ó kọ jáde jẹ́ ọmọ pupa, irun sì bo gbogbo ara rẹ̀ bí aṣọ onírun, nítorí náà, wọ́n pè é ní Ísọ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25

Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:25 ni o tọ