Jẹ́nẹ́sísì 25:27 BMY

27 Àwọn ọmọkùnrin náà sì dàgbà. Ísọ̀ sì di ọlọ́gbọ́n ọdẹ, ẹni tí ó fẹ́ràn àti máa dúró ní oko. Jákọ́bù sì jẹ́ ènìyàn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ tí ó ń gbé láàrin ìlú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25

Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:27 ni o tọ