30 Ó wí fún Jákọ́bù pé, “Ṣe kánkán, fún mi jẹ lára àsáró rẹ pupa yìí, nítorí ebi ń pa mi gidigidi.” (Ìdí èyí ni wọn fi ń pe Éṣáù ni Édómù).
Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25
Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:30 ni o tọ