Jẹ́nẹ́sísì 25:33 BMY

33 Ṣùgbọ́n, Jákọ́bù dáhùn pé, “Kọ́kọ́ búra fún mi pé tèmi ni ogún ìbí náà yóò jẹ́.” Báyìí ni Ísọ̀ búra tí ó sì gbé ogún ìbí rẹ̀ tà fún Jákọ́bù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 25

Wo Jẹ́nẹ́sísì 25:33 ni o tọ