Jẹ́nẹ́sísì 26:1 BMY

1 Ìyàn kan sì mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ fún èyí tí ó mú ní ìgbà ayé Ábúráhámù, Ísáákì sì lọ sọ́dọ̀ Ábímélékì ọba àwọn Fílístínì ni Gérárì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 26

Wo Jẹ́nẹ́sísì 26:1 ni o tọ