Jẹ́nẹ́sísì 26:24 BMY

24 Ní òru ọjọ́ tí ó dé ibẹ̀, Olúwa sì fara hàn-án, ó sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run Ábúráhámù baba rẹ: Má ṣe bẹ̀rù nítorí èmi wà fún ọ, èmi yóò sì sọ iye ìran rẹ di púpọ̀, nítorí Ábúráhámù ìránṣẹ́ mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 26

Wo Jẹ́nẹ́sísì 26:24 ni o tọ