Jẹ́nẹ́sísì 26:27 BMY

27 Ísáákì sì bi wọ́n léèrè pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin tọ̀ mí wá, níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀yin kórìra mi tí ẹ sì lé mi jáde kúrò lọ́dọ̀ yin?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 26

Wo Jẹ́nẹ́sísì 26:27 ni o tọ